ERIICE

Baille
Balẹ̀ Balẹ̀ Balẹ̀ Balẹ̀ Iná ń'ọkàn mi Ọ n jó bi iná Ifẹ̀ re tí mu mi Ko wun mi ka ma ṣepe Òjò nlá tí mo ri Ifẹ̀ rẹ ti n ṣo mi dédé Mo mo pe eeyan ni Ko ni fi mi s'ílẹ̀ Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀ L'ójú rẹ ni mo wa Eyin temi ni gbogbo re O loju mi bi kékeré Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀ L'ójú rẹ ni mo wa Eyin temi ni gbogbo re O loju mi bi kékeré Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀ Balẹ̀ Balẹ̀ Letras de cancionesỌkàn balẹ̀ Ẹyin temi ni gbogbo re O loju mi bi kékeré Àtún wa ni ayé Ifẹ̀ a ma p'ata O ma dùn bi oyin Iná n'ọkàn mi Rántí ọjọ́ ti o si mi Ifẹ̀ ti e gbe mi le Mo mo pe eeyan ni Ko ni fi mi sile Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀ L'ójú rẹ ni mo wa Eyin temi ni gbogbo re O loju mi bi kékeré Balẹ̀ Balẹ̀ Ọkàn balẹ̀ Eyin temi ni gbogbo re O loju mi bi kékeré Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀ L'ójú rẹ ni mo wa Eyin temi ni gbogbo re O loju mi bi kékeré Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀ L'ójú rẹ ni mo wa Eyin temi ni gbogbo re O loju mi bi kékeré From Letras Mania