Asake

Olorun
Ololade mi asake Emi kọ ọlọrun ma ni Emi kọ o ọlọrun ma ni Awa kọ oh oh Emi kọ oọlọrun ma ni Ta lo gbọn t'olorun (Ọmọ ọgbọn) Kosi anybody to lo gbon t'olorun Ti wọn ba buga ẹ oya gba fun olorun Awọn ti wọn buga mi wọn ti sapa mọ Wọn ti sapa mọ Emi kọ ọlọrun ma ni (Ọlọrun ma ni) Emi kọ o ọlọrun ma ni Awa kọ oh oh Ọlọrun ma ni (Oh oh oh) Emi kọ ọlọrun ma ni Ọmọ no be me shebi na God Carry me from down straight to the top 2020 it was real tough Fall for ground almost gave up Mo fun won lo ọmọ ọpe mo de je lo Go naked in my room and speak to God Baba god I no sabi all So guide me as I dey move on on on Letras de canciones Ta lo gbọn t'olorun Kosi anybody to lo gbon t'olorun Ti wọn ba buga ẹ oya gba fun olorun Awọn ti wọn buga mi wọn ti sapa mọ Wọn ti sapa mọ Emi kọ ọlọrun ma ni (Ọlọrun ma ni) Emi kọ o ọlọrun ma ni Awa kọ oh oh Ọlọrun ma ni (Oh oh oh) Emi kọ ọlọrun ma ni Emi kọ ọlọrun ma ni (Ọlọrun ma ni) Emi kọ o ọlọrun ma ni Awa kọ oh oh Ọlọrun ma ni (Oh oh oh) Emi kọ ọlọrun ma ni Nkan kan o gbọdọ se awọn ọmọ ologo o Mimi kan o gbọdọ mi awọn ọmọ ọlọrun o Alhamdulillah I’m a brand new man Tune in to the king of sounds and blues From Letras Mania